Download Adake Dajo by Tope Alabi: A Heartfelt Worship Anthem.
Get ready to experience the power of worship with “Adake Dajo” by Tope Alabi. This soul-stirring song is a heartfelt expression of gratitude to God for His love, mercy, and blessings. With its uplifting melody and inspiring lyrics, “Adake Dajo ” is sure to lift your spirits and draw you closer to God.
Are you searching for a sound that will uplift and bless your heart? Look no further! Cause this latest single, is a powerful worship anthem that will minister to your soul and leave you feeling refreshed and renewed.
As the Bible says in Psalm 103:2-3, “Praise the Lord, my soul, and forget not all his benefits—who forgives all your sins and heals all your diseases.”
This soul-stirring worship song is not just a melody, but a message of hope and encouragement. It’s a reminder that no matter what challenges we face, God is always good, and His love endures forever.
As you listen to this wonderful music, allow the powerful lyrics and soothing melodies to minister to your heart. Let the sound of worship wash over you, and experience the transformative power of God’s presence.
Stream “Adake Dajo” now on your favorite music platforms and immerse yourself in the presence of God. Share this amazing worship song with friends and family, drop a comment on the comment section, and let the message of gratitude and praise inspire your day.
Adake dajo On lo mo wa o, O mi wo wa w’okan Ohun gbogbo ti a gb’aye se On lo da ojiji mo wa o Ipilese aye wa ooo, at’opin re, O ri gbogbo koro
Adake dajo On lo mo wa o, O n wo wa w’okan Ohun gbogbo ti a gb’aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at’opin re, O ri gbogbo koro
Eni to da oju o, ko ni s’alairiran Olu to da eti o, ko le s’alaigboran Ko si koro loju Re, gbangba kedere lo ri gbogbo wa
Adake dajo On lo mo wa o, O n wo wa w’okan Ohun gbogbo ti a gb’aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at’opin re, O ri gbogbo koro
K’a ye s’esin, k’a ye pe e ni esin, k’a lo ja’wo pata A o le gan Olorun pelu ‘gbagbo oju tori ko ni le gba wa A n fi ti’pa gboran si ‘lana esin, ofin Olorun wa d’afieyin Opo dara loju, iwa won o dokan T’egbin t’idoti ko je k’adura opo onigbagbo o gba Ojiji t’Eleda da mo wa, o n s’afihan ohun ikoko o E o ni le gba’bode f’Olorun, onitohun a wule tan ‘ra e pa Olorun alawopa, dakun ma wo mi pa
Adake dajo On lo mo wa o, O n wo wa w’okan Ohun gbogbo ti a gb’aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at’opin re, O ri gbogbo koro
Eemo to wo ‘jo Olorun ti wa bureke, gbogbo aye di ‘ranse Olorun At’eni Baba ran, at’eni ebi le de Woli osan gangan, iyen lo bi rere Ori pepe di ‘gbale egungun At’alafose at’elepe Ogo ologo de ku t’on mi wo s’agbara Igbadi m be labe collar opo won Awon t’ogun nja t’on tori k’ogun o le se t’on wo ‘nu ijo wa O ma se arakun laso gbagi logun to n kun ogun won Ab’e o ri ijo, ki Jesu to de ki ni yio da o
Adake dajo On lo mo wa o, O n wo wa w’okan Ohun gbogbo ti a gb’aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at’opin re, O ri gbogbo koro
E je k’a bi ‘ra wa leere, gbogbo iranse Olorun pata Kini idahun si ibeere yi o Oro ijoba orun ti di ‘waasu igbaani lenu wa Ere wo lonisowo agba n je ninu ise wa E gbo ere wo, ere wo, lOluwa n je A fowoleran O ma n wo wa o Ko ma ka ‘se mi lai lere kankan Ki loo ro, ki loo so Nigba t’a ba p’oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Ki loo ro, ki loo so Nigba t’a ba p’oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so T’a ba p’oruko ni’joba orun T’a pe won titi ti o de kan e o Eni to n toka s’omo apaadi, at’eyin to mo ‘mo ile ologo T’on ba p’oruko ni’joba orun, t’on o ka mr census e ki loo ro Ki loo ro, ki loo so Nigba t’a ba p’oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Onigbagbo ka ri mi ete eke Lati inu ijo je ‘ra wa lese dede Adura at’aawe odi s’enikeji Ife ikoko lori pepe si pepe E o ranti O da ogbon o ju ogbon lo E o ba lako bi ibon lese-o-gbeji Ki loo ro, ki loo so Nigba t’a ba p’oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Ojo nla, Adajo aye fere de Aiyiwapada idajo a ro K’onikaluku lo ye ‘ra e wo Ibi t’o ba ku si, gb’adura k’o tun se Ko ma ba di ki loo ro K’enu ma wo ji, ailesoro Ki loo ro, ki loo so Nigba t’a ba p’oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Eh eh eh eh eh eh mo wi t’emi o, ore ma di’ti Ko ma di’na orun mo ‘ra e, o ti n f’ami han, Jesu o ni pe de Eru igi to n be loju re, lo gbe kuro, ko ye tenubole soro
Lo ronu ko pa iwa da, ka si toro fun aanu K’a ju’wo ju’se k’a tuba f’Olorun, K’a le ba joba, k: a le ka wa mo won Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa O n bo laipe, s’asaro aye re Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa O n bo laipe, s’asaro aye re Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa O n bo laipe, s’asaro aye re